Róòmù 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé wọn ò gbọ́ ni? Wọ́n kúkú gbọ́. Torí, ní tòótọ́, “ohùn wọn ti dún jáde lọ sí gbogbo ayé, iṣẹ́ tí wọ́n ń jẹ́ sì ti dé ìkángun ilẹ̀ ayé tí à ń gbé.”+
18 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé wọn ò gbọ́ ni? Wọ́n kúkú gbọ́. Torí, ní tòótọ́, “ohùn wọn ti dún jáde lọ sí gbogbo ayé, iṣẹ́ tí wọ́n ń jẹ́ sì ti dé ìkángun ilẹ̀ ayé tí à ń gbé.”+