5 Dáfídì àti gbogbo ilé Ísírẹ́lì ń ṣe ayẹyẹ níwájú Jèhófà pẹ̀lú onírúurú ohun ìkọrin tí a fi igi júnípà ṣe pẹ̀lú háàpù àti àwọn ohun ìkọrin míì tó ní okùn tín-ín-rín+ àti ìlù tanboríìnì+ àti sítírọ́mù pẹ̀lú síńbálì.*+
5 Ásáfù+ ni olórí, Sekaráyà ni igbá kejì rẹ̀; Jéélì, Ṣẹ́mírámótì, Jéhíélì, Matitáyà, Élíábù, Bẹnáyà, Obedi-édómù àti Jéélì+ ń ta àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù;+ Ásáfù ń lo síńbálì,*+