2 Tẹsalóníkà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Èyí jẹ́ nítorí pé Ọlọ́run kà á sí òdodo láti san ìpọ́njú pa dà fún àwọn tó ń pọ́n yín lójú.+