Sáàmù 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn tó mọ orúkọ rẹ yóò gbẹ́kẹ̀ lé ọ;+Jèhófà, ìwọ kì yóò pa àwọn tó ń wá ọ tì láé.+ Òwe 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Orúkọ Jèhófà jẹ́ ilé gogoro tó lágbára.+ Olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ààbò.*+