ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 20:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Wọ́n ń gbé ilẹ̀ náà, wọ́n sì kọ́ ibi mímọ́ síbẹ̀ fún ọ, èyí tó wà fún orúkọ rẹ,+ wọ́n sọ pé, 9 ‘Tí àjálù bá dé bá wa, ì báà jẹ́ idà tàbí ìdájọ́ tí kò bára dé tàbí àjàkálẹ̀ àrùn tàbí ìyàn, jẹ́ ká dúró níwájú ilé yìí àti níwájú rẹ (nítorí orúkọ rẹ wà nínú ilé yìí),+ ká sì ké pè ọ́ pé kí o ràn wá lọ́wọ́ nínú wàhálà wa, kí o gbọ́ kí o sì gbà wá.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́