Àwọn Onídàájọ́ 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jẹ́ kí gbogbo ọ̀tá rẹ ṣègbé,+ Jèhófà,Àmọ́ kí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ dà bí oòrùn tó ń yọ nínú ògo rẹ̀.” Àlàáfíà sì wà ní ilẹ̀ náà* fún ogójì (40) ọdún.+ Sáàmù 125:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 125 Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà+Dà bí Òkè Síónì, tí kò ṣeé mì,Àmọ́ tí ó wà títí láé.+
31 Jẹ́ kí gbogbo ọ̀tá rẹ ṣègbé,+ Jèhófà,Àmọ́ kí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ dà bí oòrùn tó ń yọ nínú ògo rẹ̀.” Àlàáfíà sì wà ní ilẹ̀ náà* fún ogójì (40) ọdún.+