2 Sámúẹ́lì 12:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Nígbà náà, ó mú adé Málíkámù kúrò ní orí rẹ̀. Ìwọ̀n adé náà jẹ́ tálẹ́ńtì* wúrà kan, pẹ̀lú àwọn òkúta iyebíye, a sì fi dé Dáfídì lórí. Ó tún kó ẹrù+ tó pọ̀ gan-an látinú ìlú náà.+
30 Nígbà náà, ó mú adé Málíkámù kúrò ní orí rẹ̀. Ìwọ̀n adé náà jẹ́ tálẹ́ńtì* wúrà kan, pẹ̀lú àwọn òkúta iyebíye, a sì fi dé Dáfídì lórí. Ó tún kó ẹrù+ tó pọ̀ gan-an látinú ìlú náà.+