Éfésù 4:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Tí inú bá bí yín, ẹ má ṣẹ̀;+ ẹ má ṣe jẹ́ kí oòrùn wọ̀ bá yín nínú ìbínú;+