4“Wò ó! ọjọ́ náà ń bọ̀, ó ń jó bí iná ìléru,+ nígbà tí gbogbo àwọn agbéraga àti gbogbo àwọn tó ń hùwà burúkú yóò dà bí àgékù pòròpórò. Ọjọ́ tó ń bọ̀ náà yóò jẹ wọ́n run,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí, “kò sì ní fi gbòǹgbò tàbí ẹ̀ka sílẹ̀ fún wọn.