Sáàmù 35:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run fi mí ṣẹ̀sín,*Wọ́n ń wa eyín wọn pọ̀ sí mi.+