Sáàmù 68:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Bá ẹranko tó wà nínú àwọn esùsú* wí,Àpéjọ àwọn akọ màlúù+ àti àwọn ọmọ màlúù,Títí àwọn èèyàn á fi tẹrí ba tí wọ́n á sì mú fàdákà wá.* Àmọ́, tú àwọn èèyàn tó fẹ́ràn ogun ká.
30 Bá ẹranko tó wà nínú àwọn esùsú* wí,Àpéjọ àwọn akọ màlúù+ àti àwọn ọmọ màlúù,Títí àwọn èèyàn á fi tẹrí ba tí wọ́n á sì mú fàdákà wá.* Àmọ́, tú àwọn èèyàn tó fẹ́ràn ogun ká.