Mátíù 26:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 wọ́n sì gbìmọ̀ pọ̀+ kí wọ́n lè fi ọgbọ́n àrékérekè* mú* Jésù, kí wọ́n sì pa á.