Sáàmù 59:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí ìwọ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+ Jí láti yí àfiyèsí rẹ sí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè. Má ṣe ṣàánú ẹnikẹ́ni tó jẹ́ ọ̀dàlẹ̀ abatẹnijẹ́.+ (Sélà) 6 Wọ́n ń wá ní ìrọ̀lẹ́ ìrọ̀lẹ́;+ Wọ́n ń kùn* bí ajá,+ wọ́n sì ń dọdẹ kiri ìlú.+ Lúùkù 22:63 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Àwọn ọkùnrin tó mú Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́,+ wọ́n ń lù ú;+
5 Nítorí ìwọ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+ Jí láti yí àfiyèsí rẹ sí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè. Má ṣe ṣàánú ẹnikẹ́ni tó jẹ́ ọ̀dàlẹ̀ abatẹnijẹ́.+ (Sélà) 6 Wọ́n ń wá ní ìrọ̀lẹ́ ìrọ̀lẹ́;+ Wọ́n ń kùn* bí ajá,+ wọ́n sì ń dọdẹ kiri ìlú.+