Sáàmù 40:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mo kéde ìhìn rere òdodo nínú ìjọ ńlá.+ Wò ó! Mi ò pa ẹnu mi mọ́,+Bí ìwọ náà ṣe mọ̀ dáadáa, Jèhófà. Hébérù 2:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ọ̀dọ̀ ẹnì kan ni ẹni tó ń sọni di mímọ́ àti àwọn tí à ń sọ di mímọ́+ ti wá,+ torí èyí ni ojú ò ṣe tì í láti pè wọ́n ní arákùnrin,+ 12 bó ṣe sọ pé: “Màá sọ orúkọ rẹ fún àwọn arákùnrin mi; màá sì fi orin yìn ọ́ láàárín ìjọ.”+
11 Torí ọ̀dọ̀ ẹnì kan ni ẹni tó ń sọni di mímọ́ àti àwọn tí à ń sọ di mímọ́+ ti wá,+ torí èyí ni ojú ò ṣe tì í láti pè wọ́n ní arákùnrin,+ 12 bó ṣe sọ pé: “Màá sọ orúkọ rẹ fún àwọn arákùnrin mi; màá sì fi orin yìn ọ́ láàárín ìjọ.”+