Jóòbù 38:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ṣé a ti fi àwọn ẹnubodè ikú+ hàn ọ́ rí,Àbí o ti rí àwọn ẹnubodè òkùnkùn biribiri?*+