-
Sáàmù 69:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Kí àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé ọ má ṣe rí ìtìjú nítorí tèmi,
Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.
Kí àwọn tó ń wá ọ má ṣe tẹ́ nítorí tèmi,
Ìwọ Ọlọ́run Ísírẹ́lì.
-