Sáàmù 103:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ wà títí ayé*Sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀+Àti òdodo rẹ̀ sí àwọn ọmọ ọmọ wọn,+ Sáàmù 136:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 136 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+
17 Àmọ́ ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ wà títí ayé*Sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀+Àti òdodo rẹ̀ sí àwọn ọmọ ọmọ wọn,+ Sáàmù 136:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 136 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+