Ẹ́kísódù 33:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ Ọlọ́run dáhùn pé: “Màá mú kí gbogbo oore mi kọjá níwájú rẹ, màá sì kéde orúkọ Jèhófà níwájú rẹ;+ èmi yóò ṣojúure sí ẹni tí èmi yóò ṣojúure sí, èmi yóò sì ṣàánú ẹni tí èmi yóò ṣàánú.”+ Sáàmù 27:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ibo ni mi ò bá wà, ká ní mi ò ní ìgbàgbọ́Pé màá rí oore Jèhófà ní ilẹ̀ alààyè?*+
19 Àmọ́ Ọlọ́run dáhùn pé: “Màá mú kí gbogbo oore mi kọjá níwájú rẹ, màá sì kéde orúkọ Jèhófà níwájú rẹ;+ èmi yóò ṣojúure sí ẹni tí èmi yóò ṣojúure sí, èmi yóò sì ṣàánú ẹni tí èmi yóò ṣàánú.”+