Sáàmù 32:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Màá fún ọ ní ìjìnlẹ̀ òye, màá sì kọ́ ọ ní ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+ Màá fún ọ ní ìmọ̀ràn pẹ̀lú ojú mi lára rẹ.+
8 “Màá fún ọ ní ìjìnlẹ̀ òye, màá sì kọ́ ọ ní ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+ Màá fún ọ ní ìmọ̀ràn pẹ̀lú ojú mi lára rẹ.+