2 Sámúẹ́lì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bóyá Jèhófà máa rí ìpọ́njú mi,+ tí Jèhófà yóò sì fi ire san án pa dà fún mi dípò èpè tí ó ń ṣẹ́ lé mi lórí lónìí yìí.”+
12 Bóyá Jèhófà máa rí ìpọ́njú mi,+ tí Jèhófà yóò sì fi ire san án pa dà fún mi dípò èpè tí ó ń ṣẹ́ lé mi lórí lónìí yìí.”+