Sáàmù 139:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mo kórìíra àwọn tó kórìíra rẹ, Jèhófà,+Mi ò sì nífẹ̀ẹ́ àwọn tó ń dìtẹ̀ sí ọ.+