Sáàmù 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Aláyọ̀ ni ẹni tí kì í tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn èèyàn burúkúTí kì í dúró ní ọ̀nà àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀+Tí kì í sì í jókòó lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹ́gàn.+
1 Aláyọ̀ ni ẹni tí kì í tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn èèyàn burúkúTí kì í dúró ní ọ̀nà àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀+Tí kì í sì í jókòó lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹ́gàn.+