-
Sáàmù 31:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 O kò fi mí lé ọ̀tá lọ́wọ́,
Àmọ́ o mú kí n dúró ní ibi ààbò.*
-
-
Sáàmù 41:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Jèhófà yóò dáàbò bò ó, yóò sì pa á mọ́.
-
-
Sáàmù 41:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ohun tí màá fi mọ̀ pé inú rẹ dùn sí mi nìyí:
Kí àwọn ọ̀tá mi má lè kígbe ìṣẹ́gun lé mi lórí.+
-