Jóòbù 33:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó ti ra ọkàn* mi pa dà kó má bàa lọ sínú kòtò,*+Ẹ̀mí mi sì máa rí ìmọ́lẹ̀.’