-
Nọ́ńbà 16:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ni Mósè bá gbéra, ó lọ bá Dátánì àti Ábírámù, àwọn àgbààgbà+ Ísírẹ́lì sì tẹ̀ lé e. 26 Ó sọ fún àpéjọ náà pé: “Ẹ jọ̀ọ́, ẹ kúrò nítòsí àgọ́ àwọn ọkùnrin burúkú yìí, ẹ má sì fara kan ohunkóhun tó jẹ́ tiwọn, kí ẹ má bàa pa run nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”
-