-
Sáàmù 59:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tó wà lẹ́nu wọn àti ọ̀rọ̀ ètè wọn,
Kí ìgbéraga wọn dẹkùn mú wọn,+
Nítorí ègún àti ẹ̀tàn tí wọ́n ń sọ lẹ́nu.