Sáàmù 56:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìwọ Ọlọ́run, ẹni tí mò ń yin ọ̀rọ̀ rẹ̀,Ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé; ẹ̀rù ò bà mí. Kí ni èèyàn* lásánlàsàn lè fi mí ṣe?+
4 Ìwọ Ọlọ́run, ẹni tí mò ń yin ọ̀rọ̀ rẹ̀,Ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé; ẹ̀rù ò bà mí. Kí ni èèyàn* lásánlàsàn lè fi mí ṣe?+