Àìsáyà 40:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó ń fún ẹni tó ti rẹ̀ ní agbára,Ó sì ń fún àwọn tí kò lókun* ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ okun.+