-
Sáàmù 88:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ṣé a lè kéde ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ nínú sàréè
Tàbí òtítọ́ rẹ ní ibi ìparun?*
-
-
Àìsáyà 38:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àwọn tó lọ sínú kòtò kò lè retí ìṣòtítọ́ rẹ.+
-