Sáàmù 143:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 143 Jèhófà, gbọ́ àdúrà mi;+Gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́. Dá mi lóhùn nínú òtítọ́ rẹ àti òdodo rẹ.