2 Sámúẹ́lì 22:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá. Sáàmù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+
3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá.
2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+