Sáàmù 23:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó tù mí* lára.+ Ó darí mi ní ipa ọ̀nà òdodo nítorí orúkọ rẹ̀.+