Àìsáyà 64:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Láti ìgbà àtijọ́, kò sẹ́ni tó gbọ́ tàbí tó fetí sílẹ̀,Kò sí ojú tó rí Ọlọ́run kankan àfi ìwọ,Tó ń gbé ìgbésẹ̀ nítorí àwọn tó ń retí rẹ̀.*+ 1 Kọ́ríńtì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́, bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ojú kò tíì rí, etí kò sì tíì gbọ́, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn èèyàn kò tíì ro àwọn ohun tí Ọlọ́run ti pèsè sílẹ̀ fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀.”+
4 Láti ìgbà àtijọ́, kò sẹ́ni tó gbọ́ tàbí tó fetí sílẹ̀,Kò sí ojú tó rí Ọlọ́run kankan àfi ìwọ,Tó ń gbé ìgbésẹ̀ nítorí àwọn tó ń retí rẹ̀.*+
9 Àmọ́, bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ojú kò tíì rí, etí kò sì tíì gbọ́, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn èèyàn kò tíì ro àwọn ohun tí Ọlọ́run ti pèsè sílẹ̀ fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀.”+