1 Sámúẹ́lì 23:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n sọ fún Sọ́ọ̀lù pé: “Dáfídì ti wá sí Kéílà.” Sọ́ọ̀lù wá sọ pé: “Ọlọ́run ti fi í lé mi lọ́wọ́,*+ nítorí ó ti há ara rẹ̀ mọ́ bó ṣe wá sínú ìlú tó ní àwọn ilẹ̀kùn àti ọ̀pá ìdábùú.”
7 Wọ́n sọ fún Sọ́ọ̀lù pé: “Dáfídì ti wá sí Kéílà.” Sọ́ọ̀lù wá sọ pé: “Ọlọ́run ti fi í lé mi lọ́wọ́,*+ nítorí ó ti há ara rẹ̀ mọ́ bó ṣe wá sínú ìlú tó ní àwọn ilẹ̀kùn àti ọ̀pá ìdábùú.”