Àìsáyà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Ní báyìí, ẹ wá, ẹ jẹ́ ká yanjú ọ̀rọ̀ láàárín ara wa,” ni Jèhófà wí.+ “Bí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín tiẹ̀ rí bí aṣọ rírẹ̀dòdò,Wọ́n máa di funfun bíi yìnyín;+Bí wọ́n tiẹ̀ pọ́n bí aṣọ tó pupa yòò,Wọ́n máa dà bí irun àgùntàn. Ìṣe 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Nítorí náà, ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì yí pa dà,+ kí Ọlọ́run lè pa àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́,+ kí àwọn àsìkò ìtura lè wá látọ̀dọ̀ Jèhófà fúnra rẹ̀,*
18 “Ní báyìí, ẹ wá, ẹ jẹ́ ká yanjú ọ̀rọ̀ láàárín ara wa,” ni Jèhófà wí.+ “Bí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín tiẹ̀ rí bí aṣọ rírẹ̀dòdò,Wọ́n máa di funfun bíi yìnyín;+Bí wọ́n tiẹ̀ pọ́n bí aṣọ tó pupa yòò,Wọ́n máa dà bí irun àgùntàn.
19 “Nítorí náà, ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì yí pa dà,+ kí Ọlọ́run lè pa àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́,+ kí àwọn àsìkò ìtura lè wá látọ̀dọ̀ Jèhófà fúnra rẹ̀,*