Sáàmù 65:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ Olùgbọ́ àdúrà, ọ̀dọ̀ rẹ ni onírúurú èèyàn* yóò wá.+ 3 Àwọn àṣìṣe mi ti bò mí mọ́lẹ̀,+Àmọ́, o dárí àwọn ìṣìnà wa jì wá.+
2 Ìwọ Olùgbọ́ àdúrà, ọ̀dọ̀ rẹ ni onírúurú èèyàn* yóò wá.+ 3 Àwọn àṣìṣe mi ti bò mí mọ́lẹ̀,+Àmọ́, o dárí àwọn ìṣìnà wa jì wá.+