Málákì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹ ó sì tún rí ìyàtọ̀ láàárín olódodo àti ẹni burúkú,+ láàárín ẹni tó ń sin Ọlọ́run àti ẹni tí kò sìn ín.” Mátíù 13:49, 50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Bó ṣe máa rí ní ìparí ètò àwọn nǹkan* nìyẹn. Àwọn áńgẹ́lì máa jáde lọ, wọ́n á ya àwọn ẹni burúkú sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn olódodo, 50 wọ́n sì máa jù wọ́n sínú iná ìléru. Ibẹ̀ ni wọ́n á ti máa sunkún, tí wọ́n á sì ti máa payín keke.
18 Ẹ ó sì tún rí ìyàtọ̀ láàárín olódodo àti ẹni burúkú,+ láàárín ẹni tó ń sin Ọlọ́run àti ẹni tí kò sìn ín.”
49 Bó ṣe máa rí ní ìparí ètò àwọn nǹkan* nìyẹn. Àwọn áńgẹ́lì máa jáde lọ, wọ́n á ya àwọn ẹni burúkú sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn olódodo, 50 wọ́n sì máa jù wọ́n sínú iná ìléru. Ibẹ̀ ni wọ́n á ti máa sunkún, tí wọ́n á sì ti máa payín keke.