-
Hébérù 11:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ìgbàgbọ́ jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ló mú kí àwọn ètò àwọn nǹkan* wà létòlétò, tó fi jẹ́ pé ohun tí à ń rí jáde wá látinú àwọn ohun tí a kò rí.
-