Ìfihàn 14:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ń sọ̀rọ̀ tó dún ketekete pé: “Ẹ bẹ̀rù Ọlọ́run, kí ẹ sì fi ògo fún un, torí wákàtí tó máa ṣèdájọ́ ti dé,+ torí náà, ẹ jọ́sìn Ẹni tó dá ọ̀run àti ayé àti òkun+ àti àwọn ìsun* omi.”
7 Ó ń sọ̀rọ̀ tó dún ketekete pé: “Ẹ bẹ̀rù Ọlọ́run, kí ẹ sì fi ògo fún un, torí wákàtí tó máa ṣèdájọ́ ti dé,+ torí náà, ẹ jọ́sìn Ẹni tó dá ọ̀run àti ayé àti òkun+ àti àwọn ìsun* omi.”