Sáàmù 148:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ yìn ín, ẹ̀yin ọ̀run gíga jù lọ*Àti ẹ̀yin omi tó wà lókè àwọn ọ̀run. 5 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí ó pàṣẹ, a sì dá wọn.+
4 Ẹ yìn ín, ẹ̀yin ọ̀run gíga jù lọ*Àti ẹ̀yin omi tó wà lókè àwọn ọ̀run. 5 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí ó pàṣẹ, a sì dá wọn.+