Sáàmù 119:90 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 90 Òtítọ́ rẹ wà láti ìran dé ìran.+ O ti fìdí ayé múlẹ̀ gbọn-in, kó lè máa wà nìṣó.+