ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 8:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ẹ gbìmọ̀ pọ̀, àmọ́ a máa dà á rú!

      Ẹ sọ ohun tó wù yín, àmọ́ kò ní yọrí sí rere,

      Torí Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa!*+

  • Àìsáyà 19:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ìdààmú sì máa bá Íjíbítì láàárín rẹ̀,

      Màá sì da àwọn ohun tó ń gbèrò rú.+

      Wọ́n máa yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí,

      Àwọn atujú, àwọn abẹ́mìílò àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́