1 Sámúẹ́lì 21:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dáfídì fi ọ̀rọ̀ wọ̀nyí sọ́kàn, ẹ̀rù sì bẹ̀rẹ̀ sí í bà á gan-an+ nítorí Ákíṣì ọba Gátì. 13 Torí náà, ó díbọ́n lójú wọn bíi pé orí òun ti yí,+ ó sì ń ṣe bí ayírí láàárín wọn.* Ó ń ha ara àwọn ilẹ̀kùn ẹnubodè, ó sì ń wa itọ́ sí irùngbọ̀n rẹ̀.
12 Dáfídì fi ọ̀rọ̀ wọ̀nyí sọ́kàn, ẹ̀rù sì bẹ̀rẹ̀ sí í bà á gan-an+ nítorí Ákíṣì ọba Gátì. 13 Torí náà, ó díbọ́n lójú wọn bíi pé orí òun ti yí,+ ó sì ń ṣe bí ayírí láàárín wọn.* Ó ń ha ara àwọn ilẹ̀kùn ẹnubodè, ó sì ń wa itọ́ sí irùngbọ̀n rẹ̀.