Jóòbù 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó sì sọ fún èèyàn pé: ‘Wò ó! Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ọgbọ́n,+Yíyẹra fún ìwà burúkú sì ni òye.’”+ Òwe 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbẹ̀rù* Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀.+ Àwọn òmùgọ̀ ni kì í ka ọgbọ́n àti ìbáwí sí.+ Òwe 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+
13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+