Mátíù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Aláyọ̀ ni àwọn tó ń wá àlàáfíà,*+ torí a máa pè wọ́n ní ọmọ Ọlọ́run. Hébérù 12:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ máa lépa àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn+ àti ìsọdimímọ́,*+ tó jẹ́ pé láìsí i, èèyàn kankan ò lè rí Olúwa.
14 Ẹ máa lépa àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn+ àti ìsọdimímọ́,*+ tó jẹ́ pé láìsí i, èèyàn kankan ò lè rí Olúwa.