Òwe 24:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje, á sì tún dìde,+Àmọ́ àjálù yóò mú kí ẹni burúkú ṣubú pátápátá.+ 2 Tímótì 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ó dájú pé gbogbo àwọn tó bá fẹ́ fi ayé wọn sin Ọlọ́run tọkàntọkàn ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù ni wọ́n máa ṣe inúnibíni sí pẹ̀lú.+
16 Nítorí olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje, á sì tún dìde,+Àmọ́ àjálù yóò mú kí ẹni burúkú ṣubú pátápátá.+
12 Ó dájú pé gbogbo àwọn tó bá fẹ́ fi ayé wọn sin Ọlọ́run tọkàntọkàn ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù ni wọ́n máa ṣe inúnibíni sí pẹ̀lú.+