Sáàmù 18:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi alágbára,+Lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra mi, tí wọ́n sì lágbára jù mí lọ.+