Hábákúkù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ojú rẹ ti mọ́ jù láti wo ohun búburú,Ìwọ kò sì ní gba ìwà burúkú láyè.+ Kí ló wá dé tí o fi fàyè gba àwọn ọ̀dàlẹ̀,+Tí o sì dákẹ́ títí ẹni burúkú fi gbé ẹni tó jẹ́ olódodo jù ú lọ mì?+
13 Ojú rẹ ti mọ́ jù láti wo ohun búburú,Ìwọ kò sì ní gba ìwà burúkú láyè.+ Kí ló wá dé tí o fi fàyè gba àwọn ọ̀dàlẹ̀,+Tí o sì dákẹ́ títí ẹni burúkú fi gbé ẹni tó jẹ́ olódodo jù ú lọ mì?+