Sáàmù 71:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ahọ́n mi yóò máa sọ nípa* òdodo rẹ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+Ojú yóò ti àwọn tó ń wá ìparun mi, wọ́n á sì tẹ́.+
24 Ahọ́n mi yóò máa sọ nípa* òdodo rẹ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+Ojú yóò ti àwọn tó ń wá ìparun mi, wọ́n á sì tẹ́.+