Sáàmù 103:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí bí ọ̀run ṣe ga ju ayé,Bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tó ní sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ ṣe ga.+